Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Olive Tree: Israelites commanded to cultivate in the land of promise
Àwọn ẹsẹ nípa Israelites commanded to cultivate in the land of promise
Ìwọ yóò ní igi olifi jákèjádò ilẹ̀ rẹ ṣùgbọ́n ìwọ kò ní lo òróró náà, nítorí olifi náà yóò rẹ̀ dànù.