Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obed-Edom: 3. A conservator of the vessels of the temple in time of Amaziah
Àwọn ẹsẹ nípa 3. A conservator of the vessels of the temple in time of Amaziah
Ọba kó gbogbo wúrà àti fàdákà àti gbogbo ohun èlò tí wọ́n rí ni ilé Ọlọ́run tí ọ́ wà ní àbojútó Obedi-Edomu, lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ìṣúra ààfin àti àwọn ògo pẹ̀lú, ó sì padà lọ sí Samaria.