Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obed-Edom: 2. A doorkeeper of the temple
Àwọn ẹsẹ nípa 2. A doorkeeper of the temple
Ó fi Obedi-Edomu àti méjìdínláàádọ́rin ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ láti ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ pẹ̀lú wọn. Obedi-Edomu mọ Jedutuni, àti Hosa pẹ̀lú jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà.