Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nimrim: Waters on the borders of Gad and Moab.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Waters on the borders of Gad and Moab.

  1. Gbogbo omi Nimrimu ni ó ti gbẹ àwọn koríko sì ti gbẹ, gbogbo ewéko ti tán ewé tútù kankan kò sí mọ́.

  2. “Ohùn igbe wọn gòkè láti Heṣboni dé Eleale àti Jahasi, láti Soari títí dé Horonaimu àti Eglati-Ṣeliṣi, nítorí àwọn omi Nimrimu pẹ̀lú yóò gbẹ.