Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Missions: The first to do homage to the Messiah were heathen
Àwọn ẹsẹ nípa The first to do homage to the Messiah were heathen
Bí wọ́n tí wọ inú ilé náà, wọn rí ọmọ ọwọ́ náà pẹ̀lú Maria ìyá rẹ̀, wọ́n wólẹ̀, wọ́n foríbalẹ̀ fún un. Nígbà náà ni wọ́n tú ìṣúra wọn, wọ́n sì ta Jesu lọ́rẹ: wúrà, tùràrí àti òjìá.