Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mishael: 1. A son of Uzziel, helps carry the bodies of Nadab and Abihu out of the camp
Àwọn ẹsẹ nípa 1. A son of Uzziel, helps carry the bodies of Nadab and Abihu out of the camp
Àwọn ọmọ Usieli ni: Miṣaeli, Elsafani àti Sitiri.
Mose pe Miṣaeli àti Elsafani ọmọ Usieli tí í ṣe arákùnrin Aaroni, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ wá, kí ẹ sì gbé àwọn arákùnrin yín jáde kúrò níwájú ibi mímọ́ lọ sí ẹ̀yìn ibùdó.”