Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mercy: Characteristic of saints
Àwọn ẹsẹ nípa Characteristic of saints
Aláàánú ni òun nígbà gbogbo a máa yá ni; a sì máa bùsi i fún ni.
Olódodo ṣègbé kò sí ẹnìkan tí ó rò ó lọ́kàn ara rẹ̀; a mú àwọn ẹni mímọ́ lọ, kò sì ṣí ẹni tó yé pé a ti mú àwọn olódodo lọ láti yọ wọ́n kúrò nínú ibi.