Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Merari: Head of the Merarite Levites

4 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Head of the Merarite Levites

  1. Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari.

  2. Ti Merari ni ìran Mahili àti Muṣi, àwọn ni ìran Merari.

  3. Iye gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, èyí tí wọ́n kà jẹ́ igba mọ́kànlélọ́gbọ̀n (6,200).

  4. Olórí àwọn ìdílé ìran Merari ni Ṣurieli ọmọ Abihaili. Wọn yóò pa ibùdó wọn sí ìhà àríwá àgọ́.