Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meat Offerings: To be eaten by the males of the house of Aaron alone
Àwọn ẹsẹ nípa To be eaten by the males of the house of Aaron alone
Èyíkéyìí nínú àwọn ọmọkùnrin ìran Aaroni ló le jẹ ẹ́. Èyí ni ìpín rẹ tí ó gbọdọ̀ máa ṣe déédé lára àwọn ẹbọ tí a fi iná sun sí Olúwa láti ìrandíran. Ohunkóhun tí ó bá kàn án yóò di mímọ́.’ ”