Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Journey of Israel Through The Desert: Several of these stations probably revisited
Àwọn ẹsẹ nípa Several of these stations probably revisited
Wọ́n kúrò ní Haṣmona wọ́n sì pàgọ́ ní Moserotu.
Wọ́n kúrò ní Moserotu wọ́n sì pàgọ́ ní Bene-Jaakani.
Wọ́n kúrò ní Bene-Jaakani wọ́n sì pàgọ́ ní Hori-Haggidgadi.