Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jair: 1. Son of Manasseh, founder of twenty-three cities in Gilead
Àwọn ẹsẹ nípa 1. Son of Manasseh, founder of twenty-three cities in Gilead
Segubu sì jẹ́ baba Jairi, ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìlú mẹ́tàlélógún ní ilẹ̀ Gileadi.
(Ṣùgbọ́n Geṣuri àti Aramu sì fi agbára gba Hafoti-Jairi, àti Kenati pẹ̀lú gbogbo agbègbè rẹ̀ tí wọn tẹ̀dó sí jẹ́ ọgọ́ta ìlú.) Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Makiri baba Gileadi.