Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Idleness and Sloth: Effects of, afford instruction to others

3 ẹsẹ · 18 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Effects of, afford instruction to others

  1. Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn;

  2. ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà.

  3. Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí;