Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Idleness and Sloth 3 ẹsẹ · 18 abala Wá "Idleness and Sloth" Gbogbo 3 Effects of, afford instruction to others 3 Accompanied by conceit · Akin to extravagance · Athenians · Bondage · Disappointment · False excuses for · Forbidden · Hunger · Illustrated · Poverty · Produce apathy · Remonstrance against · Ruin · Tattling and meddling · Thessalonians · Want · Watchmen · Fi gbogbo 19 hàn Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Òwe 24:30Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn;Òwe 24:31ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà.Òwe 24:32Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí;