Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Hamath: Conquest of, by the Chaldeans
Àwọn ẹsẹ nípa Conquest of, by the Chaldeans
Nebusaradani, olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ kó gbogbo wọn, ó sì mú wọn tọ ọba Babeli wá ní Ribla.
Níbẹ̀ ní Ribla, ní ilẹ̀ Hamati, ọba Babeli sì kọlù wọ́n. Bẹ́ẹ̀ ni a mú Juda kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.