Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Flattery: Danger of 3 ẹsẹ · 20 abala Wá "Flattery" Gbogbo 17 General references 9 Absalom 5 Danger of 3 Avoid those given to · Darius's courtiers · False prophets · False prophets and teachers use · God · Ministers should not use · Others · People of Tyre, &c · Pharisees, &c · Punishment of · Saints should not used · Seldom gains respect · Themselves · Those in authority · Wisdom, a preservative against · Woman of Tekoah · Worldly advantage obtained by · Fi gbogbo 21 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Danger of Òwe 7:21Pẹ̀lú ọ̀rọ̀ dídùn ó sì í lọ́nà; ó tàn án jẹ pẹ̀lú ẹnu dídùn.Òwe 7:22Òun sì tọ̀ ọ́ lọ lẹsẹ̀ kan náà, bí i màlúù tí ń lọ sí ibi pípa, tàbí bí àgbọ̀nrín tí ń lọ sí ibi okùn ìso.Òwe 7:23Títí tí ọ̀kọ̀ fi gún un ní ẹ̀dọ̀, bí ẹyẹ ṣe ń fẹ́ wọ inú okùn, láìmọ̀ pé yóò gba ẹ̀mí òun.