Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Feast of Tabernacles: Design of

2 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Design of

  1. Ẹ gbé inú àgọ́ fún ọjọ́ méje. Kí gbogbo ọmọ bíbí Israẹli gbé nínú àgọ́.

  2. Kí àwọn ìran yín le mọ̀ pé mo mú kí Israẹli gbé nínú àgọ́, nígbà tí mo mú wọn jáde ní Ejibiti. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.’ ”