Skip to content

Sibbechai

5 ẹsẹ

A tún mọ̀ ọ́n sí: Sibbecai, Mebunnai

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Sibbechai

  1. Lẹ́yìn èyí, ìjà kan sì tún wà láàrín àwọn Israẹli àti àwọn Filistini ní Gobu, nígbà náà ni Sibekai ará Huṣati pa Safu, ẹni tí í ṣe ọ̀kan nínú àwọn Rafa.

  2. Abieseri ará Anatoti, Sibekai ará Huṣati;

  3. Sibekai ará Huṣati, láti ará Ahohi

  4. Ní ẹ̀yìn èyí ni ogun bẹ́ sílẹ̀ ní Geseri pẹ̀lú àwọn ará Filistini, ní àkókò yìí ni Sibekai ará Huṣati pa Sipai, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Refaimu, àti àwọn ará Filistini ni a ṣẹ́gun.

  5. Ẹ̀kẹjọ fún oṣù kẹjọ jẹ́ Sibekai ará Huṣati, ará Sera ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀.