Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ezion-Gaber: Last encampment of Israel before coming to the »wilderness of Zin«
Àwọn ẹsẹ nípa Last encampment of Israel before coming to the »wilderness of Zin«
Wọ́n kúrò ní Abrona wọ́n sì pàgọ́ ní Esioni-Geberi.
Wọ́n kúrò ní Esioni-Geberi wọ́n sì pàgọ́ ní Kadeṣi nínú aginjù Sini.