Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Early Rising: Neglect of, leads to poverty

3 ẹsẹ · 65 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Neglect of, leads to poverty

  1. Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò dùbúlẹ̀, ìwọ ọ̀lẹ? Nígbà wo ni ìwọ yóò jí kúrò lójú oorun rẹ?

  2. Oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera láti sinmi díẹ̀.

  3. Òsì yóò sì wá sórí rẹ bí ìgárá ọlọ́ṣà àti àìní bí adigunjalè.