Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Communion of Saints: Exhortation to 3 ẹsẹ · 22 abala Wá "Communion of Saints" Gbogbo 16 Opposed to communion with the wicked 4 Delight of 3 Exhortation to 3 Paul 3 Saints in heaven 3 According to the prayer of Christ · Apostles · Christ is present in · Daniel · David · Each other · God · God marks, with his approval · In exhortation · In holy conversation · In mutual comfort and edification · In mutual sympathy and kindness · In prayer for each other · In public and social worship · In the Lord's supper · Jonathan · The Church · Fi gbogbo 23 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Exhortation to Efesu 4:1Nítorí náà, èmi òǹdè nínú Olúwa ń bẹ̀ yín pé kí ẹ̀yin máa gbé ìgbé ayé tí ó yẹ sí ìpè tí a pè yín sí.Efesu 4:2Pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀ gbogbo àti inú tútù, pẹ̀lú ìpamọ́ra, ẹ máa fi ìfẹ́ faradà fún ẹnìkejì yín.Efesu 4:3Kí ẹ sì máa làkàkà láti pa ìṣọ̀kan Ẹ̀mí mọ́ ni ìdàpọ̀ àlàáfíà.