Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Chilion: A son of Naomi.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A son of Naomi.

  1. Wọ́n sì fẹ́ àwọn ọmọbìnrin ará Moabu méjì, orúkọ ọ̀kan ń jẹ́ Oripa, èkejì sì ń jẹ́ Rutu. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n sì ti gbé níbẹ̀ fún bí ọdún mẹ́wàá,

  2. Maloni àti Kilioni náà sì kú, Naomi sì wà láìsí ọkọ tàbí ọmọ kankan fún un mọ́.