Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Chilion 2 ẹsẹ · 1 abala Wá "Chilion" Gbogbo 2 A son of Naomi. 2 Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Rutu 1:4Wọ́n sì fẹ́ àwọn ọmọbìnrin ará Moabu méjì, orúkọ ọ̀kan ń jẹ́ Oripa, èkejì sì ń jẹ́ Rutu. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n sì ti gbé níbẹ̀ fún bí ọdún mẹ́wàá,Rutu 1:5Maloni àti Kilioni náà sì kú, Naomi sì wà láìsí ọkọ tàbí ọmọ kankan fún un mọ́.