Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Chastity: Drunkenness destructive to 3 ẹsẹ · 21 abala Wá "Chastity" Gbogbo 60 General references 44 Preserved by wisdom 5 Joseph 4 Keep the body in 4 Consequences of associating with those devoid of 3 Drunkenness destructive to 3 Temptation to deviate from, dangerous 3 Want of, excludes from heaven 3 Abimelech · Advantages of · Boaz · Breach of, punished · Commanded · Motives for · Required in heart · Required in look · Required in speech · Ruth · Saints are kept in · Shun those devoid of · The wicked are devoid of · Fi gbogbo 22 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Drunkenness destructive to Òwe 23:31Ìwọ má ṣe wò ọtí wáìnì nígbà tí ó pọ́n, nígbà tí ó bá ń fi àwọ̀ rẹ̀ hàn nínú ago, tí a gbé e mì, tí ó ń dùn.Òwe 23:32Níkẹyìn òun á bu ni ṣán bí ejò, a sì bunijẹ bí i paramọ́lẹ̀.Òwe 23:33Ojú rẹ yóò wò àwọn àjèjì obìnrin, àyà rẹ yóò sì sọ̀rọ̀ àyídáyidà.