Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Castle: The doctrine, »The house is my castle«
Àwọn ẹsẹ nípa The doctrine, »The house is my castle«
Nígbà tí o bá wín arákùnrin rẹ ní ohunkóhun, má ṣe lọ sí ilé rẹ̀ láti gba ohun tí ó bá mú wá bí ẹ̀rí.
Dúró síta gbangba kí o sì jẹ́ kí ọkùnrin tí o wín mú ògo rẹ jáde wá fún ọ.