Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Beer-Sheba: 2. Well of, belonged to Abraham and Isaac

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. Well of, belonged to Abraham and Isaac

  1. Nígbà náà ni Abrahamu fi ẹ̀dùn ọkàn rẹ̀ hàn fún Abimeleki nípa kànga tí àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ gbà lọ́wọ́ rẹ̀.

  2. Ṣùgbọ́n Abimeleki dáhùn pé, “Èmi kò mọ ẹni tí ó ṣe nǹkan yìí. Ìwọ kò sì sọ fún mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò gbọ́, bí kò ṣe lónìí.”