Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Almon-Diblathaim: Probably identical with Diblath
Àwọn ẹsẹ nípa Probably identical with Diblath
Èmi yóò na ọwọ́ mi jáde sí wọn láti mú kí ilẹ̀ náà ṣòfò, kí ó sì dahoro dé aṣálẹ̀ ìhà Dibila—ní gbogbo ibùgbé wọn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé, Èmi ni Olúwa.’ ”