Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Allegory: Messiah's kingdom represented under, of the wolf and the lamb dwelling together

3 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Messiah's kingdom represented under, of the wolf and the lamb dwelling together

  1. Ìkookò yóò sì máa bá ọmọ àgùntàn gbé, ẹkùn yóò sì sùn ti ewúrẹ́ ọmọ màlúù òun ọmọ kìnnìún àti ọmọ ẹran ó wà papọ̀ ọ̀dọ́mọdé yóò sì máa dà wọ́n.

  2. Màlúù àti beari yóò máa jẹun pọ̀, àwọn ọmọ wọn yóò dùbúlẹ̀ pọ̀, kìnnìún yóò sì máa jẹ koríko gẹ́gẹ́ bí akọ màlúù.

  3. Ọ̀dọ́mọdé yóò ṣeré lẹ́bàá ihò ọká, ọmọdé yóò ki ọwọ́ rẹ̀ bọ ìtẹ́ paramọ́lẹ̀.