Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Agag: 2. A king of the Amalekites, taken prisoner by Saul and slain by Samuel
Àwọn ẹsẹ nípa 2. A king of the Amalekites, taken prisoner by Saul and slain by Samuel
Ó sì mú Agagi ọba Amaleki láààyè, ó sì fi idà rẹ̀ kọlù gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀.
Ṣùgbọ́n Samuẹli wí pé, “Bí idà rẹ ti sọ àwọn obìnrin di aláìní ọmọ bẹ́ẹ̀ ni ìyá rẹ yóò sì di aláìní ọmọ láàrín obìnrin.” Samuẹli sì pa Agagi níwájú Olúwa ni Gilgali.