Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Achzib: 2. Called Chezib, a city of Judah
Àwọn ẹsẹ nípa 2. Called Chezib, a city of Judah
Ó sì tún bí ọmọkùnrin mìíràn, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣela. Ní Kesibu ni ó wà nígbà tí ó bí i.
Keila, Aksibu àti Meraṣa: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò wọn.