Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Abstemiousness: General references 3 ẹsẹ · 1 abala Wá "Abstemiousness" Gbogbo 3 General references 3 Àwọn ẹsẹ nípa General references Òwe 23:1Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun, kíyèsi ohun tí ó wà níwájú rẹ gidigidi.Òwe 23:2Ìwọ a sì fi ọ̀bẹ lé ara rẹ ní ọ̀fun, bí ìwọ bá jẹ́ òkúndùn ènìyàn.Òwe 23:3Má ṣe fẹ́ oúnjẹ dídùn rẹ̀: nítorí pé oúnjẹ ẹ̀tàn ni.