Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Abib: Israelites arrive at the wilderness of Zin in
Àwọn ẹsẹ nípa Israelites arrive at the wilderness of Zin in
Ní oṣù kìn-ín-ní, gbogbo àgbájọ ọmọ Israẹli gúnlẹ̀ sí pápá Sini, wọ́n sì dúró ní Kadeṣi. Níbẹ̀ ni Miriamu kú, wọ́n sì sin ín.