Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Abia: 1. Called Abijah, chief of the twenty-four courses of priests
Àwọn ẹsẹ nípa 1. Called Abijah, chief of the twenty-four courses of priests
èkeje sì ni Hakosi, ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ sí ni Abijah,
Iddo, Ginetoni, Abijah,
Nígbà ọjọ́ Herodu ọba Judea, àlùfáà kan wà, láti ìran Abijah, orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Sekariah: aya rẹ̀ sì ṣe ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Aaroni, orúkọ rẹ̀ a sì máa jẹ́ Elisabeti.