Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Women: Consecrated jewels to tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Consecrated jewels to tabernacle
Gbogbo àwọn tí ó fẹ́, ọkùnrin àti obìnrin, wọ́n wá wọ́n sì mú onírúurú ìlẹ̀kẹ̀ wúrà: òrùka etí, òrùka àti ọ̀ṣọ́. Gbogbo wọn mú wúrà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ wá fún Olúwa.