Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wisdom: Of the princes of Issachar
Àwọn ẹsẹ nípa Of the princes of Issachar
Àti ní ti àwọn ọmọ Isakari, àwọn ẹni tí ó ní òye àkókò, láti mọ ohun tí Israẹli ìbá máa ṣe; olórí wọn jẹ́ ìgbà; àti gbogbo àwọn ìbátan wọn ń bẹ ní ìkáwọ́ wọn.