Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Pharisees: Left Judea for a time on account of
Àwọn ẹsẹ nípa Left Judea for a time on account of
Àwọn Farisi sì gbọ́ pé, Jesu ni, ó sì ń ṣe ìtẹ̀bọmi fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn púpọ̀ ju Johanu lọ.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Jesu tìkára rẹ̀ kò ṣe ìtẹ̀bọmi bí kò ṣe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀,
Ó fi Judea sílẹ̀, ó sì tún lọ sí Galili.