Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Micah: 3. Called Micha, son of Mephibosheth
Àwọn ẹsẹ nípa 3. Called Micha, son of Mephibosheth
Mefiboṣeti sì ní ọmọ kékeré kan, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mika. Gbogbo àwọn tí ń gbé ní ilé Ṣiba ni ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún Mefiboṣeti.
Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali tí ó jẹ́ baba Mika.
Àwọn ọmọ Mika: Pitoni, Meleki, Tarea, àti Ahasi.
Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika.
Àwọn ọmọ Mika: Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi.