Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Amusements and Worldly Pleasures: Lead to rejection of God
Àwọn ẹsẹ nípa Lead to rejection of God
Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa!’ Nítorí pé wọn kò fẹ́ ìmọ̀ ipa ọ̀nà rẹ.
Kí ni Olódùmarè tí àwa ó fi máa sìn in? Èrè kí ni a ó sì jẹ bí àwa ba gbàdúrà sí i?