Fò sí àkóónú
Saamu 9:19-20

Ẹ̀bẹ̀ ìkẹyìn fún ìdásílẹ̀ Ọlọ́run

Saamu 9:19-20
19
Dìde, Olúwa, má ṣe jẹ́ kí ènìyàn borí; jẹ́ kí a ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè ni iwájú rẹ.
20
Lù wọ́n pẹ̀lú ìpayà, Olúwa; jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ pé ènìyàn lásán ni wọ́n. Sela.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options