Fò sí àkóónú
Saamu 61:5-7

Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Májẹ̀mú Ayérayé Ọlọ́run

Saamu 61:5-7
5
Nítorí ìwọ ti gbọ́ àwọn ẹ̀jẹ́ mi, Ọlọ́run; Ìwọ ti fún mi ní ogún àwọn tí ó bẹ̀rù orúkọ rẹ.
6
Jẹ́ kí ẹ̀mí ọba kí ó gùn, ọdún rẹ̀ fún ìrandíran.
7
Kí ó máa jẹ ọba níwájú Ọlọ́run títí láé; pèsè àánú àti òtítọ́ rẹ tí yóò máa ṣe ìtọ́jú rẹ.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options