Fò sí àkóónú
Saamu 47:8-9

OLÚWA ń ṣàkóso lórí gbogbo orílẹ̀-èdè

Saamu 47:8-9
8
Ọlọ́run jẹ ọba lórí gbogbo kèfèrí; Ọlọ́run jókòó lórí ìtẹ́ ìwà mímọ́ rẹ̀.
9
Àwọn aládé ayé kó ara wọn jọ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn Ọlọ́run Abrahamu nítorí asà ayé ti Ọlọ́run ni, òun ni ó ga jùlọ.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options