Fò sí àkóónú
Luku 21:37-38

Àwọn ọjọ́ ìkẹyìn iṣẹ́ ìránṣẹ́ Jésù

Luku 21:37-38
37
Lọ́sàn án, Jesu a sì máa kọ́ni ní tẹmpili, lóru, a sì máa jáde lọ í wọ̀ ní òkè tí à ń pè ní Òkè Olifi.
38
Gbogbo ènìyàn sì ń tọ̀ ọ́ wá ní tẹmpili ní kùtùkùtù òwúrọ̀, láti gbọ́rọ̀ rẹ̀.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options