Fò sí àkóónú
Lefitiku 13:45-46

Àwọn ìlànà fún adẹ́tẹ̀ tí àìsàn rẹ̀ dájú

Lefitiku 13:45-46
45
“Kí ẹni tí ààrùn náà wà ní ara rẹ̀ wọ àkísà. Kí ó má ṣe gé irun rẹ̀, kí ó daṣọ bo ìsàlẹ̀ ojú rẹ̀ kí ó sì máa ké wí pé, ‘Aláìmọ́! Aláìmọ́!’
46
Gbogbo ìgbà tí ààrùn náà bá wà ní ara rẹ̀; aláìmọ́ ni, kí ó máa dágbé. Kí ó máa gbé lẹ́yìn ibùdó.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options