Skip to content
Esra 2:36-42

Esra 2:36-42

36
Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)
37
Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)
38
Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)
39
Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).
40
Àwọn ọmọ Lefi. Àwọn ọmọ Jeṣua àti Kadmieli (ti ìdílé Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74).
41
Àwọn akọrin. Àwọn ọmọ Asafu jẹ́ méjìdínláàádóje (128).
42
Àwọn aṣọ́bodè. Àwọn ará Ṣallumu, Ateri, Talmoni, Akkubu, Hatita àti Ṣobai jẹ́ mọ́kàndínlógóje (139).
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Options