Fò sí àkóónú
2 Kọrinti 1:23-24

Ìdí Pásítọ̀ Fún Ìdádúró

2 Kọrinti 1:23-24
23
Mo sì pe Ọlọ́run ṣe ẹlẹ́rìí ọkàn mi pé nítorí àti dá yín sí ní èmi kò ṣe padà sí Kọrinti.
24
Kì í ṣe nítorí tí àwa jẹ gàba lórí ìgbàgbọ́ yín, ṣùgbọ́n àwa ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú yín fún ayọ̀ yín nítorí nípa ìgbàgbọ́ ni ẹ̀yin dúró ṣinṣin.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options