Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zereda: A city or district of Ephraim.
Àwọn ẹsẹ nípa A city or district of Ephraim.
Bákan náà Jeroboamu ọmọ Nebati sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba. Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ Solomoni, ará Efraimu ti Sereda, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ opó, orúkọ rẹ̀ ni Serua.