Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zanoah: 3. A descendant of Caleb

1 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 3. A descendant of Caleb

  1. Aya rẹ̀ láti ẹ̀yà Juda sì bí Jaredi baba Gedori, àti Heberi baba Soko àti Jekutieli baba Sanoa. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin Farao Bitia, ẹni ti Meredi ti fẹ́.