Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wind: West, took away the plague of locusts from the land of Egypt
Àwọn ẹsẹ nípa West, took away the plague of locusts from the land of Egypt
Olúwa sì yí afẹ́fẹ́ náà padà di afẹ́fẹ́ líle láti apá ìwọ̀-oòrùn wá láti gbá àwọn eṣú náà kúrò ní orí ilẹ̀ Ejibiti lọ sínú Òkun Pupa. Bẹ́ẹ̀ ni ẹyọ eṣú kan kò ṣẹ́kù sí orí ilẹ̀ Ejibiti.