Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Will
Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì
Abrahamu sì fi ohun gbogbo tí ó ní fún Isaaki.
Ṣùgbọ́n kí Abrahamu tó kú, Abrahamu fún àwọn ọmọ tí àwọn àlè rẹ̀ bí fún un ní ẹ̀bùn, ó sì lé wọn jáde lọ fún Isaaki ọmọ rẹ sí ilẹ̀ ìlà-oòrùn.