Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Whore: Revenues of, not to be brought to the sanctuary
Àwọn ẹsẹ nípa Revenues of, not to be brought to the sanctuary
Ìwọ kò gbọdọ̀ mú owó iṣẹ́ panṣágà obìnrin tàbí ọkùnrin wá sí ilé Olúwa Ọlọ́run rẹ láti fi san ẹ̀jẹ́ kankan; nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ kórìíra àwọn méjèèjì.