Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Whirlwind: Speed with which God executes his purposes
Àwọn ẹsẹ nípa Speed with which God executes his purposes
Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára; Olúwa kì yóò fi àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ sílẹ̀ láìjìyà. Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú afẹ́fẹ́ àti nínú ìjì, ìkùùkuu sánmọ̀ sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.